Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè.
Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….
Dúdú – BlackÀwọ̀ Ojú Ọ̀run – BlueÀwọ̀ igi – BrownÀwọ̀ Eérú – GrayÀwọ̀ Ewé – GreenÀwọ̀ Òféfèé – OrangePupa – RedFunfun – WhitePupa rusurusu – YellowÀwọ̀ dúdú – Dark colorLight color: Àwọ̀ tí ó mọ́lẹ̀Colors: Àwọn àwọ̀ Ojú Ọ̀run dúdú díẹ̀ – The sky is blueOlógbò rẹ funfun – Your cat is white Àwọ̀ dúdú ní ó yàn láàyò – Black is his favorite colorÀwọ̀ pupa kì íṣe èyí tí ó yàn láàyò – Red is not his favorite colorÓ nwà ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ...