Home / Art / Àṣà Oòduà / Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka ní ibi ìdíje eni tí yóò jé olómoge àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.
E wo àwòrán òun pèlú Ebuka àti Bovi.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti