“615”, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀
Fẹ́mi Akínṣọlá
Awọn agba bọ wọn ni oju bayii ni alakan fii sọri.Eyi naa lo mu gomina ipinlẹ Oyo,Ṣeyi Makinde gbe igbesẹ akin, ni bi o ṣe kede ńọ́ń́bà Ẹẹfa, ookan, aarun, “615” ni ńọ́ń́bà tuntun ti ijọba ipinlẹ Ọyọ nipasẹ ajọṣepọ pẹlu ajọ ibaraẹnisọrọ, NCC gbe kalẹ fun araalu lati maa pe ni kete ti wọn ba kọlu ipenija abo ninu irinajo wọn.
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde ṣalaye pe ńọ́ń́bà naa wa fun idaabobo araalu ti wọn yoo ma lo nibẹ.
Nigba to n sọ bi ńọ́ń́bà naa yoo ṣe maa ṣiṣẹ, Gomina Seyi Makinde ni awọn olugbe ipinlẹ Ọyọ to ba n dojukọ ipenija aabo bi idigunjale, rogbodiyan, ijamba ina jijo, tabi awọn ijamba miiran lee pe fun iranwọ ajọ gbogbo to ba yẹ ni kiakia.
Gẹgẹ bi o ṣe yanana ẹ , lasiko ti awọn aṣoju ileeṣẹ ibaraẹnisọrọ NCC wa ṣe abẹwo si i ni ọfiisi gomina to wa ni Agodi nilu Ibadan loṣu Kẹjọ ọdun 2019 nibẹ ni wọn ti jiroro lori agbekalẹ nọmba naa,fun anfaani ara ilu.bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀
Ẹẹfa, ookan, aarun, “615” ni tuntun ti ijọba ipinlẹ Ọyọ nipasẹ ajọṣepọ pẹlu ajọ ibaraẹnisọrọ, NCC gbe kalẹ fun araalu lati maa pe ni kete ti wọn ba kọlu ipenija abo ninu irinajo wọn.
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde ṣalaye pe ńọ́ń́bà naa wa fun idaabobo araalu ti wọn yoo ma lo nibẹ.
Nigba to n sọ bi ńọ́ń́bà naa yoo ṣe maa ṣiṣẹ, Gomina Seyi Makinde ni awọn olugbe ipinlẹ Ọyọ to ba n dojukọ ipenija aabo bi idigunjale, rogbodiyan, ijamba ina jijo, tabi awọn ijamba miiran lee pe fun iranwọ ajọ gbogbo to ba yẹ ni kiakia.
Gẹgẹ bi o ṣe yanana ẹ , lasiko ti awọn aṣoju ileeṣẹ ibaraẹnisọrọ NCC wa ṣe abẹwo si i ni ọfiisi gomina to wa ni Agodi nilu Ibadan loṣu Kẹjọ ọdun 2019 nibẹ ni wọn ti jiroro lori agbekalẹ ńọ́ń́bà naa,fun anfaani ara ilu.