Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn ...
Read More »Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro
Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo.. Eyi ni lati fi ife otito han si ...
Read More »Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta
Ajalu ti o n sele lowo ni amai ati umuebu ni agbegbe iwo oorun ni ijoba ibile ndokwa ti owa ni ipinle delta – o ti gba ona iburu nipa pipa odomokunrin kan ti won ge apa ati ori re ...
Read More »Aawọ ni Oshodi: Oluomo, Talonskibo, Harmburger Ati Oluwo.
English Version Continue after the page break
Read More »Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe Àjọyọ̀ Ìdásílẹ̀ Àádọ́ta Ọdún
Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin. Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ si Abuja. Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ ikan ninú ipinle mẹ́fà Yorùbá. Yorùbá ni “Èkó gba olè, ó ...
Read More »IFÁ is the Divine Message of Olodumare to mankind….
” Ifa is not merely a collection of verses, proverbs, parables and anecdotes. Ifa is God’s sacred message to mankind. It is the embodiment of the totality of human existence.” Ifa is the Divine Message of Olodumare to mankind and ...
Read More »Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá
Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá. Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti ó ti ...
Read More »Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó Nparẹ́ lọ
Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i ...
Read More »Olopa pa obirin kan ni ilu Eko
Olopa yinbon pa iyawo ile kan , ni adugbo kan ti aun pe ni Onipanu ni ilu Eko, nigba ti oun le ikan ninu awon omo ti won ma un fi ero ayelujara jale. Awon agbofinro so wipe won yi ...
Read More »Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.
Ijoba ile America ti se igbekale dosinni ti (Tomahawk) oko ohun ija ofurufu ni Siria, eyi ti awon kan ti oruko won un je (Pentagon) mo nipa re ni Ọjọbọ Ni ibamu si osise, (Washington) so wipe kemikali ija ikolu ...
Read More »