Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. ...
Read More »Gobe sele lagbo Davido
Orisiirisii ara ni awon omo olorin igbalode maa n da lagbo ere orin. Iru ara bee ni bi ki won bo aso lorun ki won si ju si aarin ero onworan. Awon mii a maa bo alakorun danu soju agbo ...
Read More »Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa
Gege bi oro awon Yooba,”eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae.” Okunrin kan to pe ara re ni Cde Zenzele Nkosi lori FACEBOOK lo salaye ijamba moto to sele si i ...
Read More »Igba otun ti de: Raji Fasola ti bo soju ise
Minisita fun ina Monamona, Ise Ode, ati Ilegbee, Babatunde Raji Fasola ti kede eto ati awon igbese re akoko eleyii ti o fi ma side ise ilu ti won gbe le e lowo gege bi minisita. Gege bi gomina eleeketala ...
Read More »Kini yoo gbeyin TB Joshua leyin iku awon eniyan 116 to ku ni Synagogue?
*Igbejo dide leyin odun kan tile wo pa awon olujosin *Temitope Joshua ko lati yoju si kootu *Kini Kola Olawuyi so nipa wooli naa ko to lo sorun? Olayemi Olatilewa Temitope Babatunde Joshua Oludari ijo Synagogue, Wooli Temitope Babatunde Joshua, ...
Read More »Awon Foto Alaafin Oyo niluu London
Alaafin ti bere ayeye odun marunlelogoji (45) lori oye pelu idije ese kikan niluu London Olayemi Olatilewa Oba (Dr) Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III ti bere ajoyo ayeye odun marunlelogoji (45) to gori ite awon baba nla baba re lode ...
Read More »INEC ti kede Yahaya Bello gege bi gomina tilu dibo yan nipinle Kogi
Ajo INEC ti kede Alh. Yahaya Bello gege bi gomina tuntun tilu sese dibo yan. Ninu eto idibo eleyii ti asekagba re waye lana ni Bello lati inu egbe onigbale, APC, ti ni apapo ibo 247,752. Nigba ti PDP ni ...
Read More »Faleke faake kori nipinle Kogi
*Nje ona abayo wa fun un mo? *Nje igbeyin oro re ko ni di ti Sonroye bayii? *Kini ipa ti Tinubu ko lori oro yii? Ogbeni Abiodun Faleke to je igbakeji oludije fun ipo gomina ipinle Kogi to doloogbe, Abubakar ...
Read More »Oga olopaa yari ooo
Kosi ohun teeyan ko ni ri tan ni Naija yii sa. lol
Read More »“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee
Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe, Dokita Akintunde ti ...
Read More »