Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 75)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

idile alayo

Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...

Read More »
Yoruba

Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016

HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! ‪#‎Igba‬ o lo bi ‪#‎Orere‬.. Bee, ‪#‎Laye‬ taa wa yii ko lo bi ‪#‎Opa_ibon‬ ::::::: DAKUN ORE WA ...

Read More »
orumila

Orunmila Declared: Sooner or Later

The Ori of the rat will lead the rat to the correct ath The Ori of the Awo will lead the Awo to the path of success Sooner or later, the Ori of the fish will lead the fish to ...

Read More »
yoruba

Odo Iwoyi – 2

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...

Read More »

Eeto Owe L’esin Oro – 3

A ku deede asiko yii o ni aafin ilumoye, moki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa OWE L’ESIN ORO, oro l’esin owe ti oro ba sonu owe ni a o fi waa jade. Ope nla lo si ...

Read More »
aso iyi ile yoruba

Ogulutu Oro Toni – 24.05.2016

Wo binu ba nbio masoro, tinu re basi ndun mase ile ri, fi eniyan buburu sile saye re. # wo Mase mura lati gbija arare fija le f’OLOHUN,ohun nikan loba elesan….. Ire oo  

Read More »
Yoruba

Iwure Owuro Toni – 24.05.2016

E MAA WI TELE MI : ………. *Eledumare tete wa pa mi lerin ayo. *Ajalu buruku ko ni sele si mi. *Edumare ba mi segun alatako. *Emi ko ni subu fun ota yo. *Apari inu mi ko ni ba tode ...

Read More »
yoruba religion

Lori Eto Tonii: Kini nje Ela ?

* Kin ni nje ELA ? Abi Taani ‪#ELA‬ je gan-an ? * Nje ‪‎ESIN‬ ati ‪#ASA‬ Yoruba tako ara won bi ? * Bawo ni ‪# Ela_boru‬ , ‪ Ela Boye‬ , ‪  Ela bo sise‬ se je Ede ikini fun ...

Read More »
yoruba religion

Check out Top 13 Babalawos in the U.S

The more the merrier. I think the esoteric word of Olodumare(ifa) is spreading so fast in United States of America. Imagine these Babalawos almost the same time in the States. 1. Araba Ifayemi Elebuibon- Osogbo origin 2. Araba Awodiran Agboola- ...

Read More »
adekunle

Oro re e gbe ye wo

hmnmmmmmm ojulu oooo!, E gbo nti omodekunrin olorin yi(adeekunle gold) nfi orin nwi? O nipe okunrin olowo-agbaye(aliko-dangote) yi ko ni ori-meji o ni oun nan fe lowo bi dangote oun fe gun moto-boginni(range-rover) oun fi kadara we karaole oun fi ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb