Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »Ofiisi Fasola tuntun: Ise minisita ti bere ni perewu
Minisita fun ise ode, mona-mona ati eto ilegbe ti bere ise lofiisi re tuntun lana ojo Aje, Monde.
Read More »Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...
Read More »Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa
Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge. Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.
Read More »Dayo Amusa ti pada senu ise
Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...
Read More »Eleleture lati owo Akeem Lasisi
Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE
Read More »Somi Edumare lati owo Edaoto
Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to ...
Read More »Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?
Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, ...
Read More »Akoni osere onitiata: Bimbo Thomas gbayi!
Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata ...
Read More »Dapo Lam Adesina n fo lo si ilu Jamani
Omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, to tun je okan lara awon omo ile igbimo asoju-sofin ilu Abuja, Dapo Lam Adesina ti n gbera lo si ilu Jamani bayii lati lo yanju awon akanse ise ilu ti won gbe ...
Read More »