Ìlẹ̀ Amẹ́ríkà mà ti gba ipò kínní gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè tí ìtànkálẹ̀ Coronavirus ti pọ̀jù lọ l’ágbàáyé pẹ̀lú ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà márùndínláádọ́rún tó ti ní àrùn náà.
Read More »
ayangalu Comments Off on Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Nílẹ̀ Amerika Ti Ju Ti Italy Àti China Lọ!
Ìlẹ̀ Amẹ́ríkà mà ti gba ipò kínní gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè tí ìtànkálẹ̀ Coronavirus ti pọ̀jù lọ l’ágbàáyé pẹ̀lú ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà márùndínláádọ́rún tó ti ní àrùn náà.
Read More »ayangalu Comments Off on Ojúmọ́ Kan, Oògùn Kan
Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!
Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo.
Read More »ayangalu Comments Off on Olùkó̩ni Arteta ti rí ìwòsàn
Olùkó̩ni Arteta ti rí ìwòsàn Lati owo Akinwale Taophic Olukoni fun egbe agbaboolu Arsenal ni orileede England, eni ti okiki kan kaakiri ni bi ose meji seyin wi pe o ti ni aisan Coronavirus, Mikel Arteta, ni o ti je ...
Read More »ayangalu Comments Off on Manchester United Ti Se Tán Láti Ra Odion Ighalo Pátápátá
Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ronaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay
Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni akoko ninu boolu alafesegba kaakiri agbaye, Ronaldinho,
Read More »Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola
Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà, Ìyálọ́de ìlú Ìbàdàn nínú eré, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ènìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria
Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni NaijiriaÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di asiko ti a n ko iroyin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more