Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »
ayangalu Comments Off on Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »ayangalu Comments Off on Àríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano.
Read More »ayangalu Comments Off on Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ado Bayero di Emir Kano
Adi Bayero di Emir Kano Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù kẹta ọdún 2020. . Ó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá
Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọ̀ràn dé! Alárùn coronavirus di méjì ní Nàìjíríà
Lara ayewo ti ijoba apapo ati awon ajo NCDC (Nigeria Centre for Disease Control) n se pelu awon ti won ba arakunrin ara orileede Italy wo baalu ati oko po. Won n se ayewo yii naa pelu awon ti won ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè
Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun
Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku kan ti wo orileede yii lati orileede Italy.
Read More »ayangalu Comments Off on Pa Kasumu, ó dìgbà kan ná
Kayode Odumosu,papòdà lẹ́ni ọdún mẹ́tàdínláàdọ́rin Gbajúgbajà òṣèré tíátà Kayode Odumosu tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pa Kasumu ti juwọ́ ìgbẹyìn sáyé pé ó dìgbàkan. ”Èèyàn dáadáa ni wọ́n yàtọ̀ sí pé wọ́n jẹ́ òṣèré tíátà.Ikú wọ́n jẹ́ eléyìí tó fi ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more