Home / Uncategorized / Àrùn tí ó gbòde kan tí ó ń jé MONKEY POX.
monkey pox

Àrùn tí ó gbòde kan tí ó ń jé MONKEY POX.

E jòwó e jé kí á kíyè sí ara wa pèlú owó bíbò (hand shake), sísún mó ara eni tàbí ònà míràn. Àrùn kan ti gbòde ní ìpínlè Bayelsa tí won pè ní *MONKEY POX*.Àrùn tí ó máa ń ràn ni tí ó sì ti ran òpòlopò ènìyàn àti Dókítà pàápàá . Òpò ni ó wà ní ilé-ìwòsàn ifáfitì ti Niger Delta (Niger Delta Teaching Hospital (NDTUTH)) okolobiri ní ìpínlè Bayelsa…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti