Home / Art / ORIKI ORILE IREMOGUN

ORIKI ORILE IREMOGUN

oriki
Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi

About admin

One comment

  1. Ismail Abdus-Salam

    A dúpẹ́ púpọ̀ fun oríkì orílẹ̀ Ìrèmògún yìí. Ṣùgbọn kò rọrùn púpọ̀ láti kà nítorí àìní ̀àmìn ohùn lókè àti nísàlẹ̀. Ẹ jọ̀wọ́ é bá wa se àtúnkọ rẹ̀.

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

oriki esu

Oriki Esu #EsuIsNotSatan

Ẹlẹ́jẹ̀lú, Olúlànà, Ọbasìn, Láarúmọ̀, Ajọ́ńgọ́lọ̀, Ọba Ọ̀dàrà, Onílé Oríta, Ẹlẹ́gbára Ọ̀gọ, Olóògùn Àjíṣà, Láàlú Ògiri Òkò, Láàlù Bara Ẹlẹ́jọ́, Láaróyè Ẹbọra tí jẹ́ Látọpa..etc