Don't Miss
Home / Art / Àṣà Yorùbá (page 2)

Àṣà Yorùbá

Àṣà Yorùbá, Asa Ibile Yoruba,  Yoruba je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

iku

Obara-Kanhin-Kanhin

Bi-babalawo gbofa bi koba- gbo ifa , e je kafi obara kanhin kanhin looowo, Obara-kahin kanhin lo tutu toju enini lo,Obara kahin kahin awo ile Orunmila. Awon losefa fun ORUNMILA(B.A). Lojo ti IFA nbe laarin ota sangiliti,lojo ti EDU ALAJOGUN ...

Read More »
Agùnmáàníyè

Igi Agùnmáàníyè

Agùnmáàníyè ni orúkọ igi yìí, a sì máa ń lo ewée rẹ̀ fi pa kòkòrò bíi ẹ̀fọn, ìdun àti ajẹlójú-ońlé. Pẹ̀lú èyí, a kò nílò oògùn ẹ̀fọn ìgbàlódé tí ó ń ṣe àkóbá fún ìlera ara wa tí à ń ...

Read More »
buhari and osinbajo

Ó DỌWỌ́ ORÍ

Ó DỌWỌ́ ORÍ Gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá dọwọ́ Orí ẹ̀ láyé; Àlámọ̀rí ọmọ ẹ̀dá ènìyàn; Ó kúkú ń bẹ lọ́wọ́ Oríi wọn gbogbo. A díá fún PMB ẹni àyànmọ́. A bù fún PYO ẹni Orí ṣe lóore. Lọ́jọ́ tí wọn ó ...

Read More »

Ẹ̀FỌN

Ẹ̀FỌN Oníyánmú ń pa yánmú, oníyànmù ń pa yànmù, Ẹ̀fọn ń se yún-ùn yún-ùn L’étí ọmọ adáríhurun. Ẹ̀fọn kìí sùn bẹ́ẹ̀ni kòní jẹ́ k’ẹ́ni orun ń kùn ó sùn. Ẹ̀fọn ń gbọ́ pà Ẹ̀fọn ń gbọ́ pò Ìjùbàlà lọ́tùn-ún Ìjùbàlà ...

Read More »

Awon ti Ifa ba fi ran lo maa fi jise

Yoruba ronu….

Read More »

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom. Bí ó tilè jé wípé won ti sún ìdìbò síwájú látàrí àwon ìsèlè àifójúrí kan tí àwon tí ó n se ètò ìdìbo se ...

Read More »

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé.

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé. Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé se àfihàn ewà rè nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà, tí ó sì ...

Read More »
imodoye

ÌMỌ́DÒYE

An Akodi Orisa SculptureIle Ife, Nigeria January 2019Artist: Moyo Okediji

Read More »
Àkóṣe Ọ̀ràngún Méjì

Àkóṣe Ọ̀ràngún Méjì

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iná awerepèpè, a ó lọ̀ ọ́ kúnná dáadáa, a ó wà ṣa tí yóó gbẹ dáadáa. Ọ̀ràngún méjì ni a ó tẹ̀ ẹ́. A ó pe Ifá sí, a ó fi ṣín gbẹ́rẹ́ la orí já. A ó wà ...

Read More »

E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii

Eyin ara Abule, e ba ni se akiyesi aworan yii daadaa. Se kii se pe ogbeni yii fee yin ibon AK47 mo obinrin yii lapa ni? 😀 E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii, asiko wo ni isele ...

Read More »