Home / 2015 / November (page 13)

Monthly Archives: November 2015

Asake

Asake pade Lagidigba niluu London

Laipe yii ni Feyikemi Niyi-Olayinka, okan ninu awon sorosoro ori telifisan, dagbere irin-ajo re siluu London. Aworan re ni yii pelu okan lara awon osere tiata Nollywood, Sola Sobowale, niluu London. Lara awon fiimu olokiki ti Sola Sobowale se ni fiimu Lagidigba, ...

Read More »

Iyawo Buhari lo ki Tinubu laafin re

Titi aye ni olowo yoo ma sore olowo. Gbajumo yoo ma sore gbajumo nigba ti awon olosi naa yoo ma ba ara won se ninu asosiesan awon mekunnu. Aisha Buhari, aya aare ile Naijiria ti lo ki Oloye agba egbe ...

Read More »

Saheed Osupa n pada bo pelu Lord of Music

Oba orin, Saheed Osupa ti n mura lati ju awo orin tuntun kale sigboro ki odun yii to pari. Awo orin naa ni won pe ni Lord of Music eleyii ti yoo jade ninu osu December odun yii.

Read More »

Tinuola Oyindamola pegede!

Oni ni ojo-ibi Omidan Tinuola Oyindamola, okan ninu awon ti won karoyin wa lojoojumo.  Adura wa ni wi pe ke e dagba ninu ogbon, ola ati alaafia.

Read More »
baby

Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo

Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o ...

Read More »
maduaeke ati dele

Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji

Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se ...

Read More »
court

“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu

Orisun   Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...

Read More »
emir_kano

Emir tilu Kano se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram

Emir tilu Kano, Muhammadu Sanusi II, se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram to waye niluu Kano nibi ti aimoye awon eniyan ti ku.

Read More »
buhai iranu

Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.

Read More »
basket mouth

Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja

Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb