Home / Art / Àṣà Oòduà / OBARA-OSE: OBARA
OBARA-OSE OBARA

OBARA-OSE: OBARA

Eni ise nse Eni iya n je Obara pe legan o dowo loko.
Obara pe lajo o dolowo.
Obara pe lajuba o pada wa la .
O donipepe ajiki ; O di ori aji filu pe.
OSE seran seran o ni Eni a njewo fun.

This odu is one of the best in human Astra physical divination. It talk about someone who Is suffering now but will enjoy later. It’s talking about hidden wealth, Treasure yet undiscovered, and Secrets yet untold. If the client wants to do something important he should observe critically before making decisions. The client should exercise a handful of patience in all endeavors. Business-related issues will bring abundant profits later no matter how tough. The road may be rough but there is always a straight path after the tunnel. Good luck
IFA OR MI REE O.

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...