Ilu Amerika ti gbalejo Aare ile Naijiria nigba kan ri, GOODLUCK JONATHAN si Challotsville to wa ni Virginia latari igbelaruge ijoba awarawa re ati gbigbe ijoba sile ni woorowo. Ogbeni Jonathan lo sokale siluu Amerika lojo aje ana.
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more



