Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan jeri si wi pe, won ko fi owo kun owo epo won ni awon eka ile ise won to wa kaakiri ile Naijiria.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more



