Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a se n ko iroyin yii lowolowo, aja bi ogun ti jo kanle. Bakan naa ni ina naa n tesiwaju si i.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more





