ARAYE KONI LU FUN WA JO, BATA-OFO, BATA-
IBANUJE BATA-WAHALA won o ni bo si enu-
onan gbogbo wa, gbogbo eniyan tiko ba yan
Eledua l’odi e bami se ase, toripe INU-
ALAGBAFO KI LE TITI KO BINU OMI. oju-itere
ojulowo
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...