Basẹ ba mumi
Omi a tan ninu asẹ,
Bígèrè ba mumi
Omi a tan ninu ìgèrè,
ko tan ko tan lajá á lami;
Ó tán n bí ò tàn?
A ráta, a rata, ata kan ojú,
ata n tani bi ata.
Ata kuro lorẹẹ o dọta àtàtà.
‘Yee! Yee! yeee!’ ni gbogbo n ke.
Orile yii Dàdán,
Abi ko Dàdán?
”Eniyan to loun o fọ ibajẹ –
aye yii mọ,
Oluwa rẹ o kan Iyọ ninu ìdin”.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

