Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti olohun ba gbe ise ara re de. Olohun obami kuku ‘be bi ti atijo sugbon awon-eniyan ni won o sin bi ti atijo. Opo ko sin olohun pelu inu-mimo sugbon won reti ise-iyanu(miracle) be. Yoruba bo won ni aimo iso(shop) elewe ni ko je ki eniyan mo ibi tiwon ti ‘ta eko gbogbo wa pata botiwu ki oke-isoro wa ga to o nbo wa di petele pelu ase-edua.
Ojulowo Omo Yoruba Atata
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

