Home / Art / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016
asa yoruba

Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016

Hummmmmm onilari koseda tomola
‪#‎woo_orewa‬
Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye
Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni
‪#‎gbomi_dada‬
Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi
agbara ba nbe lowo re loni mase loni ilokulo nise ni
Kofi mo se omoraiye loore
‪#‎lojumo_kan‬
Gbiyanju lati ma mu inu enikan dun yio si dara fun
oooo…..ire ooooo

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.