Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa.
Ibeere
talo daran egbaafa ninu awon mejeji ??
Aku ojumo gbogbo omo kootu aji ire bi
aku faaji opin ose, mo ro wa eje ki a se jeje nitori igi iberu ni tojo
IRE O O O O O
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

