Home / Art / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
‎King Ogulutu Oro‎

Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Hummmmmm erora gbogbo yan ale yan ale
Nje
O mo wipe ohunti ntan lodun eegungun bi?
Woo Orewa
Kosi nkan towa nta ju ohun towa nile lo bi Iwo naa ba toju titie dada yio rewa yio wuyi loju
Gbomi Dada
Tete se nkan tofe se loju Ojo maso arare di apere ajase tori gbogbo awon to ngun ooo bi esin (horse) awon naa ni won o pada pie loni gba ki lo nta
Hummmmmm Seyi to se loju Ojo ma fi oko se ale koronu jinle Ojo nlo.

 

Ire oooo

 

King Ogulutu Oro

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti