Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.
iresi

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò kínní tí kò selè rí (jollof Hackathon) ti 1/0 se agbáterù rè níbi ayeye àjòdún ní Washington DC. Afropolitan insight ló se àgbékalè ètò náà.

Omidan Ogunsalu fi hàn fún gbogbo èèyàn wípé ní tòótó àwon ènìyàn Nàìjíríà le se ìresì àsèpò tí a mò sí jollof nígbà tí ó bá orílè èdè rè gbé igbáorókè. Àwon tí won jo figagbága ní orílè èdè Cameroon, Ghana àti Sierra Leone. Òkòòkan àwon tí ó wo ìpele tí ó kéyìn yí, ni a fún ní ìséjú márùn-ún márùn-ún Láti gbé ohun tí won ti se síwàjú, Adájó tí ejó won dà lórí I Akópa; ohun tí won fé se; tí tó wò àti bí ó se sè é.

Olùgbadé tuntun omidan Ogunsalu gba Dólà lónà egbèrún kan (US$1000) gégé bi olùbásisé pò láti owó olùbá-da-isé-pò 1/0 spaces àti àwon ànfààní láti di alásè ní jollof caviar African Fusion Restaurant èyí tí won sí ní Washington DC ní odún 2009…..

Continue after the page break for English version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti