Ó ti pé tí a ti rí àwòrán Wande coal. Sùgbón èyí fi hàn wípé òré sì ni àwon méjèèjì…
Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí ó wuyì tí D’banj àti Wande coal yà tí won sì wo ara won in àwò dé eyinjú.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...