Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

   Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

Olóògbé Lawretta ni won pa…
Kí olúwa te sí aféfé rere …
Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) .
Olùkó àti Akékòó yóò ma se ìrántí re.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...