Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà.
Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà.
Won rewà gan ni.
Nse ni ó dàbi kí èmi náà bí obìnrin.
ÈṢÙ, often mistakenly equated with Satan, is a complex Orisa in the Yoruba tradition, not inherently evil. He serves as a mediator between humans and the divine, carrying messages and sacrifices. World Esu isn’t Satan 2025 Aseyisamodun to all Onisese. If you missed the first set of Photos from Esu Is Not Satan click here See more beautiful photos and videos from #EsuIsNotSatan 10067/2025 Videos