Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

    Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti lò wà ní agbede méjì esè rè.

E wo àwòrán n’ísàlè .

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. heiqhtmAn

    Ere ti won se dun ju lo je ki o gbagbe re sibe

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...