Home / Art / Àṣà Oòduà / Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.

Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.

Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ó tó di wipe ó wó.
Yóò dára bí e bá le gba ònà míràn fún àsìkò díè, kí won fi palè ojú ònà yí mó.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti