Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.

Ìgbéyàwó eka-èkó (departmental weeding) ni, ìgbéyàwó àgùnbánirò ni tí ó bèrè láti e n lé di e pèlé, tí won wá di orè tímótímó eka-èkó tí won sì padà di olólùlé eka-èkó báyìí ó ti di ìgbéyàwó eka-èkó.
Ihekuna Ann Onyekachi àti Albert Ekpedeme Slyvanus ti se tan àti se ìgbéyàwó ní ojó kerìndínlógún osù kejìlá (16/12/2017) ní odún yí ní ilé ìjosìn Holy Trinity Catholic Church Obibi, Afor-ajala tí ó wà ní ìjoba ìbílè Aboh Mbaise ní ìpínlè Imo.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...