Home / Art / Àṣà Oòduà / Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.

Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.

    Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni won ti gbé lo sí ilé ejó .

Won fi èsùn kàn wípé ó pa oko rè. Maryam kò le mú òrò náà móra ni ó bá bú sígbe gbàmù nígbà tí ó dì mó omo rè osù méfà móra.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

What is Àdìmù?

A few of my friends and students in the diaspora had asked me this question countless times, and I think it’s high time we discussed it.Please note that this is not an attempt to discredit or invalidate any practice or belief; this piece is just for us to educate one another.Now, in the Yoruba language, what does Adimu mean, or where does it originate from?Àdimu means “To hold.”The full word is Adimula, which means “to hold and prosper.”So, where does ...