Home / Art / Àṣà Oòduà / Davido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.

Davido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.

Davido àti òrébìnrin rè, Chioma wà ní Barbados báyìí báyìí láti ya àwòrán Orin tuntun tí Davido sèsè ko.
Ó ti pín àwòrán òun àti arábìnrin yí ní orí èro ayélujára tí a mò sí instagram tí ó sì ko síbè pé àsedúró ayérayé.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti