Home / Art / Àṣà Oòduà / Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).

Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).

Ni Àná tí ó jé ogbòn-ojó osù keje odún 2018, ni eka-èkó ìmò àti Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò.

Òjògbón Wole Soyinka kò gbéyìn rárá Baba náà péjú pésè níbi odún náà.

Àsèyí se àmódún. (Àse).

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Iṣẹṣe Kọ́jọ́dá/calendar – Fún Oṣù Ẹ̀bìbí/May 2025.

TÍ OSU TITUN BÁ DÉ, ARÁYÉ MÁA Ń YỌ̀ MỌ́ NI, WỌN MÁA BÁ GBOGBO WA YỌ AYỌ̀ IRE NÍNÚ OSU TITUN YÍÌ, PẸ̀LÚ ÀṢẸ ELÉDÙMARÈ . 1. Ọbàtálá/Òrìṣà-ńlá, Ọbalúayé/Ṣàpọ̀nná, Ògìrìyàn, Egúngún, Ìyàmi Àjẹ́. 2. Ifá, Ọ̀rúnmìlà, Èṣù-Ọ̀dàrà, Orí, Odù, Ọ̀ṣun, Ajé-Olókun, Ọ̀sányìn, Kórì, Ẹgbẹ́. 3. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Erinlẹ̀, Òrìṣà Oko. 4. Jàkùta/Ṣàngó, Ọya, Aganjú, Yemọja, Ìbejì, Nàná-Bùkúù. 5. Ọbàtálá/Òrìṣà-ńlá, Ọbalúayé/Ṣàpọ̀nná, Ògìrìyàn, Egúngún, Ìyàmi Àjẹ́. 6. Ifá, Ọ̀rúnmìlà, Èṣù-Ọ̀dàrà, Orí, Odù, Ọ̀ṣun, Ajé-Olókun, Ọ̀sányìn, Kórì, Ẹgbẹ́. 7. Ògún, Ìja, ...