Home / Art / Àṣà Oòduà / Timi Dakolo pín àwòrán ti ó rewà ti ìyàwó rè pèlú omo méta ní London.

Timi Dakolo pín àwòrán ti ó rewà ti ìyàwó rè pèlú omo méta ní London.

Gbajúgbajà olórin ti orílè èdè Nìjíríà, Timi Dakolo ti pín àwòrán ìyàwó rè àti àwon omo rè méta ní ìlú London, ó ko síbè wípé “wón tun ti dé baba wón tún ti dé”.

Timi Dakolo ti ó jé omo bíbí ìlú Accra ní orílè èdè Ghana tí baba rè sì jé omo Bayelsa ìlú kan ní orílè èdè Nìjíríà, orúko rè a máa jé David tí ìyá rè sí jé omo bíbí orílè èdè Ghana, orúko òun náà a máa jé Norah, tí ó kú nígbà tí Timi wà ní omo odún métàlá(13).

Bí ó tilè jé wípé omo bíbí orílè èdè Ghana ni Timi jé, tí ó sì tún ní ìwé omo ìlú ti orílè èdè Nìjíríà lówó, kò f’ìgbà kan so rí wípé omo ìlú méjì ni òun .

Njé èyí kò rewà bí?

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti