Home / Art / Àṣà Oòduà / Èèmò lukutu pébé ní ilé-èkó gíga ìfáfitì ti Ilé-ifè : Nígbà tí akékòó kan ya wèrè nígbà tí ó n kàwé lówó.

Èèmò lukutu pébé ní ilé-èkó gíga ìfáfitì ti Ilé-ifè : Nígbà tí akékòó kan ya wèrè nígbà tí ó n kàwé lówó.

Gégé bí a ti mo wípé òkan gbógì ní ilé-èkó gíga Òbafemi Awolowo University (OAU) jé ní orílè èdè Nìjíríà yí.

Sà déédéé ni a gbó wípé arábìnrin kan tí ó jé akékòó ilé-èkó yí ya wèrè látàrí ìwé kíkà nígbá yí ó jé wípé ìdánwò won ti kù sí dèdè.

Ní alé ìjeta ni ìsèlè yí selè, nígbá tí omobìnrin yí sa wèrè tán, ìwé tí ó n kà náà ló fi ñ lu ìlù. Àfi kí elédùà gbàwá ooo.

 

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...