Ogúnjó osù kejo (20/8) odoodún ni odún ìsèsi màa ń wáyé káàkiri àgbáyé.
Ìlú kòòkan ni ó sì máa ń se odún náà sùgbón àwon ìpínlè Kan wà tí won máa ń se é papò bí ìpínlè Osun.
Àjòdún odún ìsèsi àgbáyé ti odún yìí sì dùn púpò.
Àsèyí s’àmódún oooo …Àse
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

