Home / Art / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.

Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.

Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù.
Gégé bí ìròyìn se so, ègbón olóògbé so wípé ó ún so nípa èmí òkúnkún kí ó tó di wípé won kò ri mó, láti bí ojó mélòó kan sá. Ara rè ni won rí nínú omi tí ó léfòó, ní òwúrò yí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti