Home / Art / Àṣà Oòduà / Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
atiku

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku

Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.
Atiku dije du ipo Aare ni odun 1993 ni eyi ti o se ipo keta tele M K O Abiola ati Babagana Kingibe labe egbe oselu SDP.
O tun dije du ipo Aare ni odun 2007 labe egbe oselu AC sugbon ni igba ti oruko oludije jade, oruko Atiku Abubakar ko si ninu iwe INEC.
Odun 2011 ni Atiku pada si egbe PDP pelu awon gomina marun-un kan. O tun padanu ipo Aare bakan naa.
Atiku padanu ipo yii ni odun 2015 ati ni odun 2019 si owo Aare Mohammadu Buhari.
Omo Atiku ti o je komisona ni “esin kii da ni ki a ma tun un gun”, baba oun maa dije du ipo Aare ni odun 2023, o si maa jawe olubori.

Yínká Àlàbí

http://iroyinowuro.com.ng/2020/06/12/baba-mi-maa-jawe-olubori-ipo-aare%cc%a9-lo%cc%a9dun-2023-adamu-atiku/

About ayangalu

One comment

  1. SUBAIR A.O

    Ó pàdánù ìdíje ìbò ní 1993, kò rí orúkọ rẹ̀ nínú ìwé INEC ní 1997, ó tún pàdánù ìbò ní gbogbo ọdún yìí… https://t.co/AaWk1ESEHs

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

History 101: What it takes to be a MENTALLY ENSLAVED FOOL in Your ancestral Land.

History 101: What it takes to be a MENTALLY ENSLAVED Harlequin in Your ancestral Land.

The quote for today is a page from Toyin Falola’s book, ‘Yoruba Warlords of the 19th Century’. To a lot of Yoruba Muslims. Islam means servitude to Usman Dan Fodio’s estate at Sokoto. They indulge in the same idiocy that led to the fall of the great Hausa civilization. Many Yoruba Muslims from Oyo are a dangerously brainwashed set of people that would pose future danger for the preservation of Yorubaland like their ancestors who pledged allegiance to Ilorin and ...