Home / Art / Àṣà Oòduà / Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju Olorun Oba. Olayemi Oniroyin, joojumo ni mo n kogbon aye. Gbogbo igba ni mo si n ran ara mi leti wi pe asan ni duniyan, omulemofo nigbogbo re pata je. Sugbon adura kan lo wu mi ti mo fe se fun gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin, ojo ti ire ayo yin ba wole de, imo esu ko ni ba ayo naa je. Odun n lo sopin, ibanuje, o kere, o tobi, ko ni wo ile wa. A ko ni rogun ekun, idaamu, wahala, ipayinkeke ko ni yale enikeni wa. Amin.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Remigio Herrera Adeshin

Remigio Herrera Adeshina – The Legend who swallowed his sacred Ikin Ifa (See Why)

Ìbà! Babaláwo Remigio Herrera Adeshina.Ọmọ Yorùbá tí ó tan ìmólè ìṣẹ̀ṣe ní orílè-èdè Cuba. He was a renowned Babaláwo in Cuba. Born in Ijęsha Yoruba land, he was sold into slavery in the 1830s. As an Ifa priest, he trained many on Yoruba Spirituality. In 1850 he became a freeman and settled in Regla where he was well respected. Legend Remigio Herrera Adeshina has it that he swallowed his sacred Ikin Ifa (palm kernel) used for divination to take them ...