Sẹ̀gì ni ìlẹ̀kẹ̀ ọ̀bùn à bá re ẹlẹ́gbà wọn o káwọ́
A dífá fún Ọ̀rúnmìlà baba nlọ se ọkọ Ajínàbíòkú
Ifá ó to gẹ́gẹ́ kí o bámi jáwé dínà òrun mi
Ọ̀nà ikú ni kí o di
Ki o ma ma di tìfàà
Ojúmọ́ Ire
Ebo is the child of Orunmila. Orunmila created Ebo on this Earth to solve the problems of human beings. People on earth use Ebo not only to solve problems but to alleviate suffering. After the sacrifice (Etutu) is made, a Babalawo will consult Ifa to ensure that it is carried to the proper place. Ebo will then invite Esu who will then take the Etutu to heaven where it will be accepted. In this way, it is not only the ...