Home / Art / Àṣà Oòduà / Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je.  Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo to wa niluu Eko lagbo wi pe o bere ise fiimu agbelewo lodun 2006.  Omo bibi ilu Edo ni sugbon ede Yoruba eni re da saka.

About Lolade

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Egbon ati Aburo

“‘I Drank The Water Of Life Before You’: The Hidden Yoruba Wisdom Behind Ẹ̀gbọ́n & Àbúrò”

Ẹ̀gbọ́n and Àbúrò: Older or Younger Sibling In Yoruba, age matters. Even if you are only one day older than a person, you are the ẹ̀gbọ́n, and they are àbúrò. You would claim, “Mo mu omi ayé sin ẹ,” meaning “I drank the water of life before you.” You are the ẹ̀gbọ́n, and the person before whom you drank the water of life is your àbúrò. You might wonder what the significance of the terms ẹ̀gbọ́n and àbúrò is. Follow ...