Adifafun perengede Tinseyeye
Ojumomo,
Ojumotomo wa loni
Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa
Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa
Perengede Iwo ni yeye Ojumomo
Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa…….
ASHEE ASHEE WAAAA…….
Ọ̀pẹ̀lẹ̀
The actual Yoruba word for “table” is unknown to most people. Do you belong to them?It’s NOT “tabili,” hintDid you know that Ìtàfù is the proper Yoruba term for “table”? Yes. Although “tabili” is frequently used in ordinary conversation, it is essentially a borrowed term that is a Yoruba orthographic transcription of the English word “table.”However, the genuine, real Yoruba term for a table is Ìtàfù.In Yoruba, this frequently occurs: because foreign words have grown in popularity, we may forget ...