Home / Art / Àṣà Oòduà / Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita
enikan

Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita

Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii:

“Walaaahi!
Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC.
Eyin o gbagbo?

O daa naa, ipo minisita wo ni won fi okunrin yi, eni to f’emi ara re wewu lati fese rin lati ilu Eko lo siluu Abuja nitori ti Aare Buhari ati egbe oselu APC bori ibo.

Mo fe fi asiko fun aare orileede yii, Muhammadu Buhari ati egbe oselu APC ni gbedeke ojo meje lati wa ipo kan fun okunrin yii tabi ki won da ileese ijoba kan ti yoo maa ri si “Irin-are” sile. Ki won si fi maanu yi se olori re.

Bi bee ko! E ma jee ki n so nnkan ti yoo sele. Nitori, maa mobilaisi lati yo Ibadan kuro lara orileede Nigeria ni o.”

About admin

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

esuisnotsatan

LAROYÈ ÈṢÙ MOJUBA! The World Is Embracing Èṣù While Some Yorubas Still Reject Him! (Video) #EsuIsNotSatan

“Brazilian superstar Anitta just won her 1st Grammy and openly gave her reverence to Èṣù, saying, “Laroye Esu Mojuba.” Yes, you heard that right. While global icons across the diaspora honor the Orisa of fairness, communication, and divine justice on the world’s biggest stage, many at home are still clinging to colonial mistranslations (deliberate misconceptions). Dear Omo Oduduwa (Yorubas): Èṣù is not the biblical or Abrahamic Satan; you were lied to!#EsuIsNotSatan #EsuIsNotSatanWalk2026 #SayNoToCancelCulture”