Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19
Gomina kayode Fayemi ti ipinle Ekiti to darapo pelu awon gomina to ko ajakale arun coronavirus.
Fayemi kede eyi lori ero Twitter re pe saka ni ara oun da sugbon ayewo fihan pe arun naa wa lara oun.
O ni oun maa bere si ni se ijoba lati ile pelu itoju to peye.
Yínká Àlàbí
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

