Home / Art / Àṣà Oòduà / Gomina Akinwunmi Ambode gbe ami-eye fun Fasola

Gomina Akinwunmi Ambode gbe ami-eye fun Fasola


Gomina Akinwunmi Ambode ti Ipinle Eko gbe ami-eye fun gomina Ipinle Eko ana, Barisita Babatunde Fasola nibi ayeye weje-wemu olodoodun awon amofin ti Ipinle Eko

Gomina Akinwunmi Ambode eni to je alejo pataki nibi ayeye ti won pe ni Legal Year Dinner 2015/2016 eleyii to waye laipe yii ninu ogba ile iwe ti won ti n ko nipa ise amofin to wa ni Erekusu Eko lo gbe ami-eye naa fun BRF eni to se apejuwe re gege bi agba loya olori pipe.

Ti e ko ba gbagbe, ninu eto idibo abele egbe APC lati yan taani yoo soju egbe fun idije gomina Ipinle Eko ninu eto idibo odun 2015. Ogbeni Olasupo Shahore ni Fasola to je gomina to wa nipo nigba naa n ti leyin lati soju egbe. Nigba ti Bola Tinubu ati Olowo Eko, Oba Rilwan Akiolu ni Akinwunmi Ambode n’IFa mu.

Leyinoreyin, awon oludije bi mejila ni Ambode jan mole ninu eto idibo abele naa lati soju egbe APC. Eleyii to tun pada wole gege bi gomina Ipinle Eko.

 

Orisun: Olayemioniroyin.com

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ambode

EFCC Ransack #Ambode’s House in Lagos

Officials of EFCC are raiding the residence of former Governor of Lagos state, Akinwumi Ambode, in Epe, Lagos state. The Anti-graft agency had couple of weeks back frozen N9 billion traced into one of many official of Lagos government who served under him. The residence of the former governor’s chief of staff in the same Epe neighbourhood was being searched. About a couple of weeks ago, multiple bank accounts holding billions and associated with Mr Ambode were frozen as linked to the ...