English version after the page break.
Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì.
Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò.
LRU gbé okò náà kúrò lónà…
Wo òpò àwòrán sì…..
Pages: 1 2