Home / Art / Àṣà Oòduà / Òwe Tòní
Òwe Tòní

Òwe Tòní

Apọnkọ kéré ò gbọn to asọwò márà, ọgbọn asọwò márà kò tó ti ajéáwọgba, ọgbọn ajéáwọgba kò tó ti Ìyá mi ò ran mi lẹkọ̀.

The person who sells a short measure of pap is not as smart as the person who weighs it but refuses to buy, he who weighs it is not as smart as he who greets by saying you will make sales from afar, the person who just greeted without buying is as wise as the one who said my mother did not send me to buy pap.

(Over smartness makes one so gullible)

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...