Ọ̀pẹ̀lẹ̀
Ifa ni: Opele lo yo tan lo dakun de’le A difa fun peregede tii se Yeye Ojumomo. Ojumo to mo wa loni ojumo ire ni Peregede! Ifa iwo ni Yeye Ojumomo Ojumo to mo wa loni ojumo Ajé ni Peregede Ifa iwo ni Yeye Ojumomo Ojumo to mo wa loni ojumo alafia ni Peregede Ifa iwo ni Yeye Ojumomo Ojumo to mo wa loni ojumo ayo ni Peregede ifa iwo ni Yeye ojumo mo! Aase! Idowu Odeyemi