Home / News From Nigeria / Breaking News / The Odù “Ogbè Tọ́mọpọ̀n”
Odù Ogbè Tọ́mọpọ̀n

The Odù “Ogbè Tọ́mọpọ̀n”

Looking at the Odù, “Ogbè Tọ́mọpọ̀n” cast for today’s Ọ̀sẹ̀ Ifá, Ẹlẹ́rìí Ìpín enjoined us to accord respect to our greatest companion, “Ọ̀pẹ̀lẹ̀/Divining chain” at all times. Just listen to this:-

Olórìṣà ní ńṣọwọ́ òjé fìrí

Egúngún ní ńfi ọkọ́ idẹ yúnko

Adífá fún Ọ̀pẹ̀lẹ̀ èyí tíí ṣe ẹrú Ọ̀rúnmìlà

Ẹbọ kólè di ẹni ọba ní wón ní kó ṣe

Ǹjẹ́ Ọ̀pẹ̀lẹ̀, Ifá ní kí o má rẹrù mọ́

Ọba ní Ifá ńfi wá șe

Olórìṣà ní ńṣowọ́ òjé fìrí ( alias of Olúwo)

Egúngún ní ńfi ọkọ́ idẹ yúnko (alias of Olúwo)

Cast divination for Ọ̀pẹ̀lẹ̀, Divining chain, the servant of Ọ̀rúnmìlà

Ẹbọ that would make it a king to be done

Wow, Ọ̀pẹ̀lẹ̀, Ifá instructed that you should no longer be a load carrier

Ifá has made us kíngs.

Stay blessed

Àràbà of Òwòrò speaks from Sao Paulo Brazil

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

oyeku meji

Aboru Aboye: Happy Osè IFA

I hope you are doing well and goodToday ODÙ is ( Oyeku Meji )(1) igi gbonbo Agbonini ese mejeji lojija ona koropa koropa adifa fun alapa ile alu ikin fun alapa oko(2) opere loyo tan lo da ikun de ile adifa fun peregede to se omo yeye ojumomimo(3) emi oye iwo oye adifa fun Eja to se omo yeye onibu eyi to ya agan to ya apara to ri omo leyin Adiye otapuru ekun oso oko si adiye lorun woni ...