Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...
Read More »Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan
Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon ...
Read More »Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...
Read More »Arambara aso oge Mercy Aigbe tun gbode
Mercy Aigbe lo ye ki won maa pe ni Omo-ojumo-kan-aso-oge-kan. E gba bee! Eniwee, se e o gbagbe wi pe fidio Orin Femi Solar to pe ni GRACE ko ni pe jade. E le wo die ninu fidio orin naa ...
Read More »Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...
Read More »Abule wo ni sisi yii ti wa na?
Eleyii tun gaju!
Read More »Meditating about the current situation on planet earth: What Ifa Says !
Mo ṣe Iba o! “Ifa ni k’á má fi kánjúkánjú jayé, kí a má fí wàràrà lo okùn ọrọ̀. Ifa tún ní ohun tí a fi ṣe àgbà kí a má fi ṣe ìbínú nítorí ẹ̀yìnwá ọ̀la…”. Ifa si` tún ...
Read More »Question of The Day: What Is Ifa ? ( See Answer )
What Is Ifa : Ifa is a connector between Eledumare (God) and mankind. Ifa is not a Confusionist and neither he’s a traitor. Ifa explains the rationale behind wealth, sorrow, success, failure, sickness, death and the likes, and ensurs purity ...
Read More »Interesting Story: Truth may be bitter but it must be said! (Must Read)
The cheats, liars, impersonators etc have no hiding place in Ifa/Orisa religion. Listen to this from Otua Rete; B’oro ba ba ologbon omugo ni nda Adifa fun Atankoko Ogberi Ti ko gbofa ti ko gbo ‘yere ti o njehun ifa ...
Read More »E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »